Halleluyah! Oluwa seun!
Iyanu ma re o, Iyanu!
Eba mi gbe ga o!
The one true God Ese
Lati igba de igba lo n se iyanu
Olorun to lagbara, Alagbada ina
Ninu aye mi, o fi iyanu han
Igbati mo ro pe opin ti de
Ona isina di ona iyanu fun mi
Eseun Baba, Olorun to d'idajo duro
Oluwa seun fun ise iyanu re
Iyanu, Iyanu, ise iyanu re po o!
Olorun to n se iyanu ni gbogbo igba
Iyanu, Iyanu, Olorun mi o seun o!
Gbogbo aye eba mi korin iyanu
Halleluyah, Oba ti o n yipada!
Eyin to n wa iyanu, e gbo ohun Oluwa
Ko si ohun ti Olorun mi o le se
O mu ibanuje kuro, o f'ayo ropo
The one true God Ese
Iyanu l'oruko re, iyanu l'ona re
Ekueme, Olorun to n s'oro to n se e
Mo ti ri iyanu gba, mo n k'orin iyin re
Agbara re ko l'opin, Olorun mi!mi
The one true God Ese
Iyanu, Iyanu, ise iyanu re po o!
Olorun to n se iyanu ni gbogbo
The one true God Ese
Iyanu, Iyanu, Olorun mi o seun o!
Gbogbo aye eba mi korin iyanu
Halleluyah, Oba ti o n yipada!
The one true God Ese
Iyanu lo n se!
Olorun iyanu o seun o!
Halleluyah! Amin!