Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (E gbo!)
Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (E ma gbagbe!)
Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (Se e ti gbo?)
Mase jale, mase k'egbekegbe
Mase huwa ti ko da, kiyesi iwa re
Opolopo omo lo n jale kiri (Ah ah!)
Isekuse, isokuso, iwakiwa
Ti ko ba opolopo omo (E ma se be!)
Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (E ma gbagbe!)
Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (Se e ti gbo?)
Eyin alaigboran, e lo sora (E sora o!)
Omo ti ko gbo t'obi, e lo sora
Iya nbe f'omo ti ko gbo, e lo sora
Iwo omo mi, iwo omo mi
B'awon elese ba n tan o, iwo mase gba (Ma gba o!)
Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (E ma gbagbe!)
Eyin Omo oooo, Eyin Omo
E gboran si awon obi l'enu (Se e ti gbo?)
Sora, sora, sora oooooo, omo mi (Sora!)
Olorun a ran o lowo, amin
Eyin obi, e f'adura ran won lowo ni gbogbo igba
Ki won le wulo fun ogo Olorun
L'oruko Jesu, amin! (Alagbara!)