Baba wa bamise, kaye mi nitumon si rere
Baba wa bamise, kaye mi nitumon si rere (2x)
Lodun tia wayi ni ko mase
D'odun to nbo, Oluwa bamise temi
Baba wa bamise, Oluwa tête see
Moti gbiyanju titi baba mio rona abayo
Moti Sare titi Oluwa ofo lo jasi o baba
Ninu odun yi, mase gbagbe mi
Oluwa wa gbami lowo won
Baba wa bamise, kaye mi nitumon si rere (2x)
Lodun tia wayi ni ko mase
D'odun to nbo, Oluwa bamise temi
Ogun eniyan lo yimika nibi gbogbo timo bati lo
Arayé buru o, omo eniyan soro
Yeee, Oluwa wa gbami lowo won
Mo gbiyanju lati se rere o
Ijakule lojasi o, aayé le Oluwa dide o
Aayé le Oluwa gbami o
Wa gbemileke asebi Olorun mo bebe
Ma koja mi, Olugbala gbo adura mi
Gbatiwo ba npelomiran mase koja mi
Jesu, Jesu gbo adura mi
Baba wa bamise
Oluwa tête see, ninu odun yi
Mase gbagbe mi, eeeeeeeee