Mo duro n'íwájú Rẹ, O mọ gbogbo ohun ti ń ṣẹlẹ̀ ninu mi
Reset my heart, clear my mind, make it new
Tan ina yi soke — ki ó jó fun Ọ nikan
Use my life, take my hands
Lo àyè mi, lo ọwọ́ mi, lo ohun gbogbo ti mo ni
Chorus:
Use me, Lord, be Your hands in the broken places
Lo mi, Baba, ki n le ran àwọn tó n'ílò ìrànlọ́wọ́
Use me, Lord, be Your voice when there’s no words to say
Dahun si mi, ki ohun Rẹ sọrọ níbi ìdákẹ́jẹ́
Dá mi lọlá pẹ̀lú ọ̀pọ̀ ìbùkún, ki igbesi aye mi di ìtàn ọpé
So I can be a blessing to my generation and those after me
Kí n le jẹ́ ìbùkún fún iran mi àti àwọn tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi
Move through me, let Your light break through
So when they see me, they see Your glory .
I’m not here for clout, I’m here for Your name
Mi ò wá f'orúkọ mi, ṣùgbọ́n orúkọ Rẹ ni mo ń gbé sókè
Don’t need the spotlight, just give Your name the glory you deserve
If I speak, let it be what You put in me
Ti mo bá sọrọ, jẹ́ kí ó jẹ́ ọ̀rọ̀ Rẹ tí o gbé sínu mi,
If I live, let it lead every heart back to you ,
*Ìwàláàyè mi, jẹ́ kí ó mú gbogbo ọkàn padà wá sí Ọ,
Chorus:
Use me, Lord, be Your hands in the broken places
Lo mi, Baba, ki n le ran àwọn t'o nílò ìrànlọ́wọ́
Use me, Lord, be Your voice when there’s no words to say
Dahun si mi, ki ohun Rẹ sọrọ níbi ìdákẹ́jẹ́
Dá mi lọlá pẹ̀lú ọ̀pọ̀ ìbùkún, kí ìgbésí ayé mi di ìtàn opé
So I can be a blessing to my generation and those after me
Move through me, let Your light break through
So when they see me, they see Your glory.
When my faith gets thin and the road feels cold
Nígbà tí ìgbàgbọ́ mi bá ń kéré, ti ọ̀nà ń fẹ́ dàrú
Remind me You’re working, even when I can’t see it unfold
Hold me steady when I start to slip
Dí mi mú ṣinṣin nígbà tí ẹsẹ̀ mi bá ń yọ́
You’ve never disengaged, so I won’t let go
Fọ́ àwọn ẹ̀wọ̀n náà, ṣhí ilẹ̀kun tí kò fẹ́ ṣhí
Make me an answer for the ones in the struggle
Jẹ́ kí n jẹ́ ìdáhùn fún àwọn tí ìṣòro ń pa l'ẹ́kún
Put Your love in my hands, put Your words on my tongue
Fi ifẹ́ Rẹ sínu ọwọ́ mi, fi ọ̀rọ̀ Rẹ sí mi l'énu
Let me be where the healing has just begun
Jẹ́ kí n wà níbi tí ìwòsàn ti ń bẹ̀rẹ̀
Bridge:
Lead: When I feel small
All: Ìwọ sì ń lo àwọn ẹni ti Ayé ò l'érò!
Lead: When I lose focus
Final Chorus: Use me, Lord, be Your hands in the broken places
Lo mi, Baba, ki n le ran àwọn t'ó n'ílò ìrànlọ́wọ́
Use me, Lord, be Your voice when there’s no words to say
Dahun si mi, ki ohun Rẹ sọrọ níbi ìdákẹ́jẹ́*
Da mi lọlá pẹ̀lú ọ̀pọ̀ ìbùkún, ki igbesi aye mi di ìtàn opé
So I can be a blessing to my generation and those after me
Move through me, let Your light break through
So when they see me, they see Your glory.
God, make me, Om'Oba Kétu Your response to those in the struggles,
Dá mi lọlá lọ́pọ̀lọpọ̀, make the channel of Your blessings
For my generation and for the ones who’ll take my place
Fún iran mi àti àwọn tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi
Healing, hope, love that never ends
Use me now, use me again and again Baba God.