Ona Olorun o, ona Olorun o
Ona ti Olorun gba soro
Lati se ise Re
Ona Re ti enikankan ko mo
Awa maridini
Ogo fun Baba orun
E je ka yin oruko Re
A o maa gbadura si O
Titi opin aye
Alaigbagbo won yio sina
Won ko ise Oluwa
Awon to gba Oluwa gbo
Won ki yio pofo laiye
Hallelujah, amin
Awon to gba Oluwa gbo
Won ki yio pofo laiye
Amin, amin
A o maa sin O titi aye
A o korin iyin Re
Iwo ni Oba awon oba
Olorun ti o tobi ju
Ogo ati ola fun O
E je ka gbe Jesu ga
A o maa tele Re titi
Titi a o fi de orun
Alaigbagbo won yio sina
Won ko ise Oluwa
Awon to gba Oluwa gbo
Won ki yio pofo laiye
Hallelujah, amin
Awon to gba Oluwa gbo
Won ki yio pofo laiye
Amin, amin
Oluwa daabo bo wa
Fi anu Re han wa
A o maa fi gbogbo okan wa
Sin O titi aye
Ogo fun Jesu
Ogo fun Baba
Ogo fun Emi Mimo
Lailai, amin
Ona Olorun o, hallelujah
Awon to gba Oluwa gbo
Won ki yio pofo laiye, amin