[female vocals] Olorun
lo
Mon
okan
to
nsin
niwaju
olorun 2
x
hoooooo 2
x.
Gbogbo
wa
lawa
lati
josin
ninu
ile
olorun,
elomiran
a
jo
titi
ninu
ile
olorun,
se
olorun
wa
nibe,
ko
lo
mon
dahun
sinu
re.
Olorun
lo
mon
okan
to
nsin
niwaju
olorun 2
x
hoooooo 2
x.
Okan
wa
l'olorun
nberé
tia
bati
wa
nibi,
ironun
tia
gbewa
yen
o
ko
nan
olorun
lohun
kan.
Bi
a
bawa
niwaju
baba
Ejeka
ma
a
sora,
Orisirisi
ero
yoma
farahan,
omo
olorun
oo
Ejeka
sora.
Vocale..
Olorun
loke
ee
a
wa
niwaju
re.
Choriste...
Wa
funwa
lemin
isin
nilé
olorun.
Vocale...
Gbogbo
erokero
tohu
kole
gba
okan
wa.
Choriste.,.
Wa
funwa
lemin
isin
nilé
olorun.
Vocale..
Mase
jé
kawa
lasan
oo
olorun
agbaye.
Choriste..
Wa
funwa
lemin
isin
nilé
olorun.
Vocale...
Olu
orun
ooo
oré
ofe
la
beré
fun.
Choriste..
Wa
funwa
lemin
isin
nilé
olorun