(Ad-lib:
Emi
Mimo,
wa,
wa
o!) (
Ad-lib:
Baba,
a
n
pe
o,
wa
tunmise!)
Fowotomi,
Baba,
Fowotomi
omo
Fowotomi
Emi
Mimo,
wa
ramipada
o
Iwo
ni
Alamo
to
momi,
ko
soun
ti
o
le
se
Fowotomi,
Emi
Mimo,
wa
ramipada
A
n
ke
pe
o,
wa
tun
ayemi
se
Ko
s'oun
to
soro
fun
o,
Baba
Dide
Olorun
mi,
tete
dide
Dide
soro
aye
mi,
koju
ma
timi
o
Dide
Olorun
mi,
tete
dide
Dide
Olorun
mi,
tete
dide (
Ad-lib:
Dide
Baba,
dide!)
Foyin
saye
mi,
Baba,
foyin
saye
mi
Omo
foyin
saye
mi,
Emi
Mimo
Wa
tun
aye
mi
se,
aye
n
bere
wi
pe
Nibo
ni
Olorun
mi
wa?
Won
pegan
mi,
Fowotomi,
Emi
Mimo
Wa
so
egan
mi
di
ogo
Dide
Olorun
mi,
tete
dide
Dide
soro
aye
mi,
koju
ma
timi
o
Dide
Olorun
mi,
tete
dide
Olorun
to
n
gbo
ohun
ebe
Olorun
to
n
dahun
adura
Wa,
wa,
wa,
Emi
Mimo
Fi
ogo
re
han
ninu
aye
mi
Dide
Olorun
mi,
tete
dide
Dide
soro
aye
mi,
koju
ma
timi
o
Dide
Olorun
mi,
tete
dide
Dide
Olorun
mi,
tete
dide (
Ad-lib:
Dide,
dide,
dide!) (
Ad-lib:
Ogo
ni
fun
oruko
re!) (
Ad-lib:
A
dupe,
Baba!)
Emi
Mimo,
wa!