Olorun iyin, mo gbe O ga o!
Halleluyah! Eseun Baba!
Iwo l'Olorun to n gbo adura
Iwo ni mo f'ope mi fun o o
Lati aro titi di ale
Iyin Re ko ni tan l'enu mi
Kabiyesi o, Olorun giga!
Olorun iyin, Iwo nikan l'ogo ye
Kabiyesi Re, Oba awon oba
E gbe e ga, e gbe e ga o
Olorun iyin, Eseun Baba!
Ninu riru omi aye yi
O na owo agbara Re jade
O gba mi, O gbe mi leke
Nitori naa ni mo se n f'iyin fun O
Ose o, Eseun o!
Olorun iyin, Iwo nikan l'ogo ye
Kabiyesi Re, Oba awon oba
E gbe e ga, e gbe e ga o
Olorun iyin, Eseun Baba!
Olorun iyin o, O se o!
Halleluyah, ogo ni fun Oko Re! Jéhovah you are the most high, you are the most high God