Odun Ileya tide o!
Odun Ileya tide, a dupe Alihamudulilai
Opolopo lo ti ku, ti won o ro odun
Ao fi yin won, a dupe lowo Olorun
Odun Ileya eyi, o soju emi wa
Alaga wa Aziz Ayofe, eku odun o!
E ku odun, e ku odun, Alhamdulillah!
Odun Ileya, a dupe o!
Gbogbo omo Osun ni ilu Soubre
E ku odun, Lola Allahou ao sopo re
Odun Ileya, ayo wa de o!
Lola Allahou ao sopo re!
Alihaj Latifu, baba ti ka lo soro
Odun Ileya, a dupe, Olorun se o
Gbogbo omo Osun patapata ni ilu Soubre
E ku odun, ayo wa de o!
E je ka jo ijo ti ya, ijo odun leyi o!
Odun Ileya, a dupe o!
Gbogbo omo Osun ni ilu Soubre
E ku odun, Lola Allahou ao sopo re
Lola Allahou ao sopo re!
Lola Oluwa ao sopo re
Lola Allahou ao sopo re