Refrain..Jésu oluwa n'pada bo,kini imurasilé re2x ronun re wo,y'egbagbo re wo,koma ni pe de mon o.1.. Eyin ara ninu oluwa ama n'kiyin o,iru igbagbo wo lo n follow lowolowo,se 'gbagbo aayé ni tabi ti t'oku.Refrain..jesu oluwa n'pada bo, kini imurasilé re2x ronun re wo, y'egbagbo re wo, koma ni pe de mon o.2 Orisirisi igbagbo loti gbode kan,lojo ti jesu Bade gongo a so, Refrain..jesu oluwa n'pada bo....etc 3Lojo ti jesu a yo lawo sanmon,ko momon seni tiyo mo,awon isele to nsele lofi han daju pe opin aye ti sunmon le.Refrain,. Jésu oluwa n'pada bo....etc 4.Opin ayé ti de eyin eniyan,bi ole lorun ni Jésu yo pada wa,kiyesara omo eniyan,dide oluwa oti sunmon oooooo koni pe de mon