Ah-ah, olo mi
Ife re nikan ni mo fẹ
Ehen, oya
Iyawo mi, ẹwa rẹ po pupọ
Ounje rẹ dùn mọ mi ninu
Lati igba ti mo ti rí ọ
Ayọ mi kún, kò sí wahala mọ
O lẹwà lode, o lẹwà ninu
Iyawo gidi, olùrànlọ́wọ́ mi
Olori mi, ife mi nikan soso
Iwo ni mo fẹ́ títí ayé nìṣó
Ayọ mi dọ̀tun nítorí rẹ
Iyawo mi, mo nìfẹ́ rẹ o
O tọju mi, o tọju ile wa
Bí mo ṣe n jọba, ìwọ ni ọba mi
Kò sí ẹlòmíràn bíi rẹ lálé yìí
Ife rẹ dùn ju oyin lọ o
Oṣùpá mi nínú òkùnkùn
Adùn mọ́ni lójúmọ́ gbogbo
Olo mi, aya rere
Mo nìfẹ́ rẹ títí láéláé
Kò sí gobe, ifẹ wa dára
Hẹn-ẹn, olo mi