Ilé ayé, ayé asan
Ayé imulemọfọ
Àlejò làjẹ níbẹ̀
Ọjọ́ kan là ó f'ayé yìí sílẹ̀ tá ó lọ s'ọrun
Ọjọ́ kan là ó f'ayé yìí sílẹ̀, tá ò ní rí mọ́.
Bó ti wù ká pẹ́ tò láyé (Wo!)
Ìrìn-àjò kúkúrú láyé, ìrìn-àjò kúkúrú ní ooo (Gbọ́!)
À ó padà lọ́jọ́ kan, ìyẹn dájúdájú!
Ilé ayé, ayé asan
Ayé imulemọfọ
Àlejò làjẹ níbẹ̀
Ọjọ́ kan là ó f'ayé yìí sílẹ̀ tá ó lọ s'ọrun
Ọjọ́ kan là ó f'ayé yìí sílẹ̀, tá ò ní rí mọ́.
Ọ̀rẹ́ kiyesi wa ree
Ọmọ, kíyèsí wá rèé
Bàbá, kíyèsí wá rèé
Ìyá, kíyèsí wá rèé
Àlejò làjẹ láyé o, eh, ah ah!
Àwa ń retí Rẹ, Jésù jọ̀wọ́ máa bọ̀
Tètè wá mú wa kúrò nínú ayé òṣì yìí
Wá mú wa lọ síbi ìsinmi ilu ogo
Wá mú wa lọ síbi ìsinmi (Jésù, ó dára!)
Ayé Asan, wáá muwa lo sibi
Jésu, Àwa ń retí Rẹ ,mumi duro,mumi duro,mumi duro dopin,jesu oluwa mi,mumi duro dopin.ao pade lesé jesu , nibiti Ako ni yarawa,ao rirawa,ao yo monrawa,jesu niyo se Alaga wa,mumi duro dopin........