Isokan Soubre, ogo ni fun Ọlọrun!
Chukwu mi!
Ninu ilu Soubre, isokan n jọba
Isokan, agbara,ipade Osun ninu ilu soubre koni baje lori alaga wa Aziz Ayofe ati Baba Latifu, gbogbo omo Osun patapata towa nilu soubre Ejeka fimosokan kole dara,ki alafia ki o ma joba lo laarin gbogbo wa ati awon baba wa ati awon iyawo wa ,odun ileya to nbo ka fayo ati alafia see