Hallelujah, hallelujah
Oluwa t'o se iyanu
Ninu afonifoji isoro mi
O n’owo agbara Re jade
Iyanu l’Oluwa, O l’agbara jojo
O ranti mi nigba ti ko s’enikan
Iyanu, Iyanu, Iyanu l’Oluwa
O n s’ohun nla fun mi lojoojumo
Iyanu, Iyanu, Iyanu f’okan mi
Oluwa se iyanu fun mi o, ese o
Gbogbo aye n wo mi ninu ogo Re
Ife Re l’o n r’ojo si mi lori
Lati inu ekun lo s’inu ayo nla
Iyanu Re po repete, ko l’opin
Iyanu, Iyanu, Iyanu l’Oluwa
O n s’ohun nla fun mi lojoojumo
Iyanu, Iyanu, Iyanu f’okan mi
Oluwa se iyanu fun mi o, ese o
Ese o, Baba
Iyanu l’Oluwa
Hallelujah, amin