Frobits
🎵 A song made on Frobits

Gbogbo Wa Lao Jabo

0:000:00
Download
Reply with a song
Lyrics

Gbogbo wa lao jabo,ise gbogbo tia base nile-aye, gbogbo wa lao jabo oo nigbati a Bade ijoba orun
Iwo abatenijé maa se lo
Onisokuso, elerokero
Odigba tabade ijoba orun o
Ronu igbe ayé e re wo ore
Boya t'olorun ni tabi t'esu ni
Asiko leyi omo igbala.
Gbogbo wa lao jabo
Ise gbogbo tia base nile-aye
Gbogbo wa lao jabo oo
Nigbati a bade ijoba orun
Gbogbo wa lao jabo
Ise gbogbo tia base nile-aye
Gbogbo wa lao jabo oo
Nigbati a bade ijoba orun
E wo Ijo olorun Bose nlo
Teba gbo ohun to nsele aya a ja
Se ise olorun la nse tabi tara wa?
Opo ni ko mo jesu eyin ara
O kan nwa sile olorun lasan ni
Jesu npadabo, o daju o
Gbogbo wa lao jabo
Ise gbogbo tia base nile-aye
Gbogbo wa lao jabo oo
Nigbati a bade ijoba orun
Duro, duro ti jesu o
Oré duro, ma figbala re dola
Duro ti jesu o, gba jesu Bade lati pin ère,bo j'osan tabi loru,yo ha bawa nibi tagbe sona,pelu atupa wa ti ntan,ale wipe amura tan ara,latilo sile didan,yo a bawa nibi tagbe nsona,duroooooo titi oluwa yo fi deéeeeee

More songs by popoola Listen to songs created by others
FROBITS