Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re
Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re
Iba Akoda aye, iba Aseda orun
Iba f'oba to l'ohun gbogbo
Kaabiyesi o, arugbo ojo o
Olowo ina o, Alfa ati Omega iba re
Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re
Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re
Mo juba re o Olorun t'oga
Nigbati mo wo ohun gbogbo ti e da
Orun, osupa ati irawo eeee
Tobi l'oba, gbogbo eranko ninu igbo
Won njuba Baba to nse itoju mi
E se Oluwa, awa dupe o Baba
Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re
Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re
Aaa juba re o, awa dupe o Jehovah
Lori aye mi o, ose o Baba o
Awa dupe o Jehovah, lori idile mi o ose o Baba o
Awa dupe o Jehovah, lori awon omo mi o ose o Baba o
Awa dupe o Jehovah, lori ohun gbogbo o ose o Baba o
Awa dupe o Jehovah
Iba re yee o, Olorun Eledumare iba re olorun to wa pelu idile Timothy popoola Aminnnnnnnn