Beat start...
Olorun tuwon sile, awon omo tawon bokoaram jiko lo
Olorun tuwon sile, oju re lan wo
Ni ilu Ogbomoso ni Oyo state, Oluwa dide kio gbewa nija oooo
Oju re lan wo, Olorun tuwon sile
Ogun bokoaram o titoge, Oluwa dide o
Gbawa lowo ogun bokoaram, dide toguntogun
Dide tijatija, dide alagbara
Dide Olorun mi, ko wa gbewa nija oooo
Olorun tuwon sile, awon omo tawon bokoaram jiko lo
Olorun tuwon sile, oju re lan wo
Ni ilu Ogbomoso ni Oyo state, Oluwa dide kio gbewa nija oooo
Oju re lan wo, Olorun tuwon sile
Oluwa gbewa nija patapata lowo ogun bokoaram patapata
Lowo ogun awon Fulani patapata, lowo ogun mujémújé otito gé
Gbogbo awon tiwon ti gbe lo, Oluwa gbawon la
Iwo nikan lole se Oluwa, gbawon la, mase je ko pe Oluwa a nwoju re
Baba do Wonder o, tete do Wonder, nilu Ogbomoso tete do Wonder o
Lori awon Omo wa o, tete do Wonder o
Ran agbara re sokale Oluwa awon Omo Ogun
Lori awon Omo tiwon ti gbe lo
Ran agbara re sokale Oluwa awon Omo Ogun
Baba do Wonder o, tete do Wonder o ooooo
Agbanilagbatan wa, jewô agbara re, amen